Joṣ 23:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin si ti ri ohun gbogbo ti OLUWA Ọlọrun nyin ti ṣe si gbogbo orilẹ-ède wọnyi nitori nyin; nitori OLUWA Ọlọrun nyin, on li ẹniti o ti jà fun nyin.

Joṣ 23

Joṣ 23:1-10