Joṣ 22:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Reubeni ati awọn ọmọ Gadi si sọ pẹpẹ na ni Edi: nwọn wipe, Nitori ẹrí ni li agbedemeji awa ati ẹnyin pe OLUWA on li Ọlọrun.

Joṣ 22

Joṣ 22:29-34