Joṣ 22:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin kò fi awọn arakunrin nyin silẹ lati ọjọ́ pipọ̀ wọnyi wá titi o fi di oni, ṣugbọn ẹnyin ṣe afiyesi ìlo ofin OLUWA Ọlọrun nyin.

Joṣ 22

Joṣ 22:1-4