Joṣ 22:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn olori mẹwa pẹlu rẹ̀, olori ile baba kọkan fun gbogbo ẹ̀ya Israeli; olukuluku si ni olori ile baba wọn ninu ẹgbẹgbẹrun Israeli.

Joṣ 22

Joṣ 22:7-18