Joṣ 21:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Merari gẹgẹ bi idile wọn, ní ilu mejila, lati inu ẹ̀ya Reubeni, ati inu ẹ̀ya Gadi, ati lati inu ẹ̀ya Sebuluni.

Joṣ 21

Joṣ 21:1-16