Joṣ 21:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati idile awọn ọmọ Kohati, awọn ọmọ Lefi, ani awọn ọmọ Kohati ti o kù, nwọn ní ilu ti iṣe ipín ti wọn lati inu ẹ̀ya Efraimu.

Joṣ 21

Joṣ 21:11-26