Joṣ 21:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si fi Hebroni ilu àbo fun apania pẹlu àgbegbe rẹ̀, ati Libna pẹlu àgbegbe rẹ̀, fun awọn ọmọ Aaroni alufa;

Joṣ 21

Joṣ 21:3-23