Joṣ 2:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin na lepa wọn li ọ̀na ti o lọ dé iwọ̀do Jordani: bi awọn ti nlepa wọn si ti jade lọ, nwọn tì ilẹkun ẹnubode.

Joṣ 2

Joṣ 2:2-17