Joṣ 2:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Obinrin na si mú awọn ọkunrin meji na, o si fi wọn pamọ́; o si wi bayi pe, Awọn ọkunrin kan wá sọdọ mi, ṣugbọn emi kò mọ̀ ibi ti nwọn ti wá.

Joṣ 2

Joṣ 2:1-10