Joṣ 19:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati gbogbo ileto ti o yi ilu wọnyi ká dé Baalati-beeri, Rama ti Gusù. Eyi ni ilẹ-iní ẹ̀ya awọn ọmọ Simeoni gẹgẹ bi idile wọn.

Joṣ 19

Joṣ 19:1-18