Joṣ 19:41-44 Yorùbá Bibeli (YCE)

41. Àla ilẹ-iní wọn si ni Sora, ati Eṣtaolu, ati Iri-ṣemeṣi;

42. Ati Ṣaalabbini, ati Aijaloni, ati Itla;

43. Ati Eloni, ati Timna, ati Ekroni;

44. Ati Elteke, ati Gibbetoni, ati Baalati;

Joṣ 19