Joṣ 19:39-42 Yorùbá Bibeli (YCE)

39. Eyi ni ilẹ-iní ẹ̀ya awọn ọmọ Naftali gẹgẹ bi idile wọn, ilu wọnyi pẹlu ileto wọn.

40. Ilẹ keje yọ fun ẹ̀ya awọn ọmọ Dani gẹgẹ bi idile wọn.

41. Àla ilẹ-iní wọn si ni Sora, ati Eṣtaolu, ati Iri-ṣemeṣi;

42. Ati Ṣaalabbini, ati Aijaloni, ati Itla;

Joṣ 19