Joṣ 18:26-28 Yorùbá Bibeli (YCE)

26. Ati Mispe, ati Kefira, ati Mosa;

27. Ati Rekemu, ati Irpeeli, ati Tarala;

28. Ati Sela, Elefu, ati Jebusi (ti iṣe Jerusalemu), Gibeati, ati Kitiria; ilu mẹrinla pẹlu ileto wọn. Eyi ni ilẹ-iní awọn ọmọ Benjamini gẹgẹ bi idile wọn.

Joṣ 18