Joṣ 18:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si ṣẹ́ keké fun wọn ni Ṣilo niwaju OLUWA: nibẹ̀ ni Joṣua si pín ilẹ na fun awọn ọmọ Israeli gẹgẹ bi ipín wọn.

Joṣ 18

Joṣ 18:1-18