Joṣ 17:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati awọn ọmọ Israeli ndi alagbara, nwọn mu awọn ara Kenaani sìn, ṣugbọn nwọn kò lé wọn jade patapata.

Joṣ 17

Joṣ 17:8-17