Joṣ 16:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Àla na jade lọ lati Tappua si ìha ìwọ-õrùn titi dé odò Kana; o si yọ si okun. Eyi ni ilẹ-iní ẹ̀ya awọn ọmọ Efraimu gẹgẹ bi idile wọn;

Joṣ 16

Joṣ 16:7-10