Joṣ 16:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn kò si lé awọn ara Kenaani ti ngbé Geseri jade: ṣugbọn awọn ara Kenaani joko lãrin Efraimu titi di oni yi, nwọn si di ẹrú lati ma sìnru.

Joṣ 16

Joṣ 16:1-10