Joṣ 12:21-24 Yorùbá Bibeli (YCE)

21. Ọba Taanaki, ọkan; ọba Megiddo, ọkan;

22. Ọba Kedeṣi, ọkan; ọba Jokneamu ti Karmeli, ọkan;

23. Ọba Doru, li òke Doru, ọkan; ọba awọn orilẹ-ède Gilgali, ọkan;

24. Ọba Tirsa, ọkan; gbogbo awọn ọba na jẹ́ mọkanlelọgbọ̀n.

Joṣ 12