Joṣ 11:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si jade, awọn ati gbogbo ogun wọn pẹlu wọn, ọ̀pọlọpọ enia, bi yanrin ti mbẹ li eti okun fun ọ̀pọ, ati ẹṣin ati kẹkẹ́ pipọ̀pipọ.

Joṣ 11

Joṣ 11:1-12