Joṣ 10:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Joṣua gòke lati Gilgali lọ, on ati gbogbo awọn ọmọ-ogun pẹlu rẹ̀, ati gbogbo awọn alagbara akọni.

Joṣ 10

Joṣ 10:6-15