Joṣ 10:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si kọja lati Libna lọ si Lakiṣi, ati gbogbo Israeli pẹlu rẹ̀, o si dótì i, o si fi ìja fun u.

Joṣ 10

Joṣ 10:27-40