Joṣ 10:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Joṣua wipe, Ẹ ṣi ẹnu ihò na, ki ẹ si mú awọn ọba mararun na jade kuro ninu ihò tọ̀ mi wá.

Joṣ 10

Joṣ 10:13-27