Joṣ 1:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣe giri, ki o si mu àiya le: nitori iwọ ni yio pín ilẹ na fun awọn enia yi, ilẹ ti mo ti bura fun awọn baba wọn lati fi fun wọn.

Joṣ 1

Joṣ 1:5-8