Jer 9:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sa wò o, ọjọ mbọ̀ li Oluwa wi, ti emi o jẹ gbogbo awọn ti a kọ ni ilà pẹlu awọn alaikọla ni ìya;

Jer 9

Jer 9:19-26