Jer 9:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli wi; sa wò o, awọn enia yi pãpa ni emi o fi wahala bọ́, emi o si mu wọn mu omi orõro.

Jer 9

Jer 9:12-20