Jer 8:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awon iyokù ti o kù ninu idile buburu yi yio yan kikú jù yiyè lọ: ni ibi gbogbo ti nwọn kù si, ti emi ti tì wọn jade si, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.

Jer 8

Jer 8:1-6