Jer 7:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bi ẹnyin ba tun ọ̀na ati ìwa nyin ṣe nitõtọ; ti ẹnyin ba ṣe idajọ otitọ jalẹ, ẹnikini si ẹnikeji rẹ̀.

Jer 7

Jer 7:1-8