Jer 7:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sibẹ nwọn kò gbọ́ temi, bẹ̃ni nwọn kò tẹti wọn silẹ, sugbọn nwọn mu ọrun le, nwọn ṣe buburu jù awọn baba wọn lọ.

Jer 7

Jer 7:19-27