Jer 7:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin si wá, ẹ si duro niwaju mi ni ile yi, ti a fi orukọ mi pè! ẹnyin si wipe: Gbà wa, lati ṣe gbogbo irira wọnyi?

Jer 7

Jer 7:4-11