Jer 6:29-30 Yorùbá Bibeli (YCE)

29. Ẹwìri joná, iná ti jẹ ojé, ẹniti nyọ ọ, nyọ ọ lasan, a kò si ya enia buburu kuro.

30. Fàdaka bibajẹ ni enia yio ma pè wọn, nitori Oluwa ti kọ̀ wọn silẹ.

Jer 6