Jer 6:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ile wọn o di ti ẹlomiran, oko wọn ati aya wọn lakopọ̀: nitori emi o nà ọwọ mi si ori awọn olugbe ilẹ na, li Oluwa wi.

Jer 6

Jer 6:3-16