Jer 52:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ogun awọn ara Kaldea lepa ọba, nwọn si ba Sedekiah ni pẹtẹlẹ Jeriko, gbogbo ogun rẹ̀ si tuka kuro lọdọ rẹ̀.

Jer 52

Jer 52:5-10