Ati ipin onjẹ rẹ̀, ipin onjẹ igbagbogbo, ti ọba Babeli nfi fun u lojojumọ ni ipin tirẹ̀, titi di ọjọ ikú rẹ̀, ni gbogbo ọjọ aiye rẹ̀.