Jer 52:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ibinu Oluwa, o ri bẹ̃ ni Jerusalemu ati Juda, titi o fi tì wọn jade kuro niwaju rẹ̀. Sedekiah si ṣọtẹ si ọba Babeli.

Jer 52

Jer 52:1-13