Jer 52:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pomegranate mẹrindilọgọrun li o wà ni gbangba: gbogbo pomegranate lori iṣẹ wiwun na jẹ ọgọrun yikakiri.

Jer 52

Jer 52:18-29