Jer 52:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ọwọ̀n mejeji, giga ọwọ̀n kan ni igbọnwọ mejidilogun; okùn igbọnwọ mejila si yi i ka; ninipọn wọn si jẹ ika mẹrin, nwọn ni iho ninu.

Jer 52

Jer 52:12-22