Jer 51:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Babeli ṣubu, a si fọ ọ lojiji: ẹ hu fun u; ẹ mu ikunra fun irora rẹ̀, bi o jẹ bẹ̃ pe, yio san fun u.

Jer 51

Jer 51:1-17