Jer 51:55 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe Oluwa ti ṣe Babeli ni ijẹ, o si ti pa ohùn nla run kuro ninu rẹ̀; riru wọn si nho bi omi pupọ, a gbọ́ ariwo ohùn wọn.

Jer 51

Jer 51:47-61