Jer 51:48 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọrun ati aiye, ati gbogbo ohun ti o wà ninu wọn, yio si kọrin lori Babeli: nitori awọn afiniṣeijẹ yio wá sori rẹ̀ lati ariwa, li Oluwa wi.

Jer 51

Jer 51:43-50