Jer 51:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa awọn ọmọ-ogun ti fi ẹmi rẹ̀ bura pe, ni kikún emi o fi enia kún ọ gẹgẹ bi ẹlẹnga; nwọn o si pa ariwo ogun lori rẹ.

Jer 51

Jer 51:12-15