Jer 5:30-31 Yorùbá Bibeli (YCE)

30. Ohun iyanu ati irira li a ṣe ni ilẹ na.

31. Awọn woli sọ asọtẹlẹ eke, ati awọn alufa ṣe akoso labẹ ọwọ wọn, awọn enia mi si fẹ ki o ri bẹ̃; kini ẹnyin o si ṣe ni igbẹhin rẹ̀?

Jer 5