Jer 5:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ gbọ́ eyi nisisiyi, ẹnyin aṣiwere enia ati alailọgbọ́n; ti o ni oju, ti kò si riran, ti o ni eti ti kò si gbọ́.

Jer 5

Jer 5:19-26