Jer 49:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si gbe itẹ mi kalẹ ni Elamu, emi o si pa ọba ati awọn ijoye run kuro nibẹ, li Oluwa wi.

Jer 49

Jer 49:34-39