Jer 49:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hasori yio di ibugbe fun ọ̀wawa, ahoro titi lai: kì o si ẹnikan ti yio joko nibẹ, bẹ̃ni ọmọ enia kan kì yio ṣatipo ninu rẹ̀.

Jer 49

Jer 49:26-36