Jer 49:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si Kedari, ati si ijọba Hasori, ti Nebukadnessari ọba Babeli, kó: Bayi li Oluwa wi; Dide, goke lọ si Kedari, ki ẹ si pa awọn ọkunrin ìla-õrùn run.

Jer 49

Jer 49:24-33