Jer 49:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi ti fi ara mi bura, li Oluwa wi pe: Bosra yio di ahoro, ẹ̀gan, idahoro, ati egún; ati gbogbo ilu rẹ̀ ni yio di ahoro lailai.

Jer 49

Jer 49:3-23