Jer 48:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

A fi Moabu ṣe ijẹ, ẽfin ilu rẹ̀ si goke lọ, awọn àṣayan ọdọmọkunrin rẹ̀ si sure lọ si ibi pipa, li Ọba wi, ẹniti orukọ rẹ̀ ijẹ, Oluwa awọn ọmọ-ogun.

Jer 48

Jer 48:10-24