Jer 46:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Egipti dide bi odò Nile, omi rẹ̀ si nrú bi omi odò wọnni; o si wipe, Emi o goke lọ, emi o si bò ilẹ aiye, emi o si pa ilu ati awọn olugbe inu rẹ̀ run!

Jer 46

Jer 46:2-13