Jer 46:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ohùn inu rẹ̀ yio lọ gẹgẹ bi ti ejo; nitori nwọn o lọ pẹlu agbara; pẹlu àkeke lọwọ ni nwọn tọ̀ ọ wá bi awọn akégi.

Jer 46

Jer 46:19-28