Jer 46:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ, ọmọbinrin ti ngbe Egipti, pèse ohun-èlo ìrin-ajo fun ara rẹ: nitori Nofu yio di ahoro, a o si fi joná, laini olugbe.

Jer 46

Jer 46:14-24